BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìkọlù Yobe: Wo dúkìá àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìrin Dapchi
1 Ẹrẹ̀nà 2018
Àwọn ákọroyín BBC ya àwòrán dúkìá àádọ́fà akẹ́kọ̀ọ́bìrin tí wọ́n jí gbé ní Dapchi.
Àkọlé àwòrán,
Ìjọba Nàìjííà ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé àwọn àádọ́fà akẹ́kọ̀ọ́bìrin ni ágbébọn Boko Haram jí lọ
Àkọlé àwòrán,
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìrin náà fi ilé-ìwé wọn sílẹ̀ láì dágbérẹ
Àkọlé àwòrán,
Àwọn kan nínú àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìrin náà kò ní ànfàànì àti wọ bàtà wọn
Àkọlé àwòrán,
Àwọn dúkìá táwọn akẹ́kọ̀ọ́bìrin Dapchi fisílẹ̀ di àwòrán ìrántí wọn
Àkọlé àwòrán,
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìrin kan tí wọ́n móríbọ́ ní àwọn kò ní padà sílé ìwé náà mọ́
Àkọlé àwòrán,
Kò sẹ́ni tó mọ ibití àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìrin Dapchi wà di àsìkò yìí
Àkọlé àwòrán,
Ìjọba Nàijíríà tí táàri baálu lọ sí agbegbe náà lati wá àwọn akẹ́kọbìrín náà wá
Àkọlé àwòrán,
Sùgbọn nísín yíì òfífó nile-ìwé àwọn akẹ́kọ náà wà
Móríwú
01:03
Fídíò,
Àwọn ọ̀dọ̀ ilẹ̀ Africa ni ìlera ọpọlọ wọn pé jù lọ láàgbáyé-Ìwádìí
, Duration 1,03
04:54
Fídíò,
Agboolé Akọni: Ohun tó fa ìjà láàárín Afonja àti Aláàfin Aole àti bí Alimi ṣe dìtẹ̀gbàjọba lọ́wọ́ Afonja nítorí ẹ̀sìn
, Duration 4,54
01:27
Fídíò,
Ohun tó máa ń mú kí ọkùnrin máa rí àpẹrẹ pé òun lóyún nígbà tí ìyàwó rẹ̀ bá lóyún; COUVAD sydrome ni, ohun tó sì ń fàá rèé
, Duration 1,27
04:16
Fídíò,
Torí pé àwọn èèyàn ò rí ààrín èmi àti Allwell Ademola ni wọ́n fi ń sọ pé a ń fẹ́ra, àmọ́ Ọlọ́run yan án sínú ayé mi láti tọ́ mi sọ́nà – Rotimi Salami oṣere
, Duration 4,16
00:59
Fídíò,
Àwọn awakọ̀ ti bẹ̀rẹ̀ sí ní tò ra epo pẹ̀lú bí owó epo ṣe ń lọ sókè
, Duration 0,59
03:03
Fídíò,
Wo tọkọtaya tó ń gba àwẹ̀ Lent àti Ramadan papọ̀
, Duration 3,03
01:44
Fídíò,
Wo àkóbá tó wà nínú àgbàdo, ẹ̀wà àti ata tí a lọ̀ ní ẹ̀rọ ìlọta fún ẹ̀dọ̀ àti kíndìnrín rẹ
, Duration 1,44
05:52
Fídíò,
Ohun táwọn oníṣẹ̀ṣe sọ fún àjọ INEC lórí ìdìbò àti pàtàkì ọdún Ọ̀ṣun Osogbo tí wọ́n fi yí ọjọ́ ìdìbò gómìnà padà
, Duration 5,52
01:01
Fídíò,
Bí àwọn ọmọ orílẹ̀èdè Iran kan ṣe ń dunnú, làwọn míràn ń kẹ́dún lórí ikú Ayatollah Ali Khamenei olórí Iran
, Duration 1,01
01:20
Fídíò,
Fes el Bali, ìlú 'Mẹ́dínà kékéré' tí ẹ̀sìn àti àṣà ìṣẹ̀mbáyé ti pàdé ara wọn
, Duration 1,20
04:01
Fídíò,
Omi Arinta, omi ńlá tó máa ń yọ̀ nígbàkúgbà tó bá rí ènìyàn ní àyíká rẹ̀
, Duration 4,01
02:42
Fídíò,
Bí nǹkan oṣù rẹ̀ bá ń gba èékánná, ìdodo, àtẹ́lẹwọ́ àtàwọn ẹ̀yà ara tó yàtọ̀ sí ojú ara jáde, ọ̀nà àbáyọ rèé
, Duration 2,42
Trending Now