BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Àwòràn ọdún egúngún ilu Ìwó jẹ́ àwòpadà-sẹ́yìn
12 Ògún 2018
Àwọn àwòrán yìí ló jẹ ojú ní gbèsè nípa ọdún egúngún 2018 tó wáyé ní ìlú Ìwó.
Àkọlé àwòrán,
O gbẹnu tan fun egungun to n lo irukẹrẹ bii ọba
Àkọlé àwòrán,
Ibadi egungun yii dara nijo
Àkọlé àwòrán,
Ọdọ lo n gbe egungun ni abi agba ?
Àkọlé àwòrán,
Ẹni ti ko lee rin ni ki wọn gbe oun lasiko ọdun egungun ilu Iwo.
Àkọlé àwòrán,
Ẹku oni leesi, fun eegun igbalode la ba pe ẹku yii
Àkọlé àwòrán,
Egungun alare ree o pẹlu ilu ati ijo to sọkutu-wọwọ
Àkọlé àwòrán,
Egungun ọlọmọ yọyọ ree, n se lo ko ọmọ yọyọ sẹyin
Àkọlé àwòrán,
Ẹni to ba gba pasan meji sara ninu awọn pasan yii, yoo wa ibi wọ si ni
Àkọlé àwòrán,
Ẹni to ba sẹ ọmọde yii, ko tete ba ẹsẹ rẹ sọrọ, atori yii lee mu ki gende bu sẹkun
Àkọlé àwòrán,
Ẹgan ni ẹ, awon eeyan woran ọdun eegun 2018 nilu Iwo
Àkọlé àwòrán,
Tilu-tifọn ni awọn eeyan ilu Iwo fi ki awọn ara ọrun kaabọ
Àkọlé àwòrán,
Awọn obinrin gan ja ọrẹ lasiko ọdun eegun ọdun yii
Àkọlé àwòrán,
Ara meriri ma tun leyi, ewo ni ti odo lẹyin egungun
Móríwú
01:03
Fídíò,
Àwọn ọ̀dọ̀ ilẹ̀ Africa ni ìlera ọpọlọ wọn pé jù lọ láàgbáyé-Ìwádìí
, Duration 1,03
04:54
Fídíò,
Agboolé Akọni: Ohun tó fa ìjà láàárín Afonja àti Aláàfin Aole àti bí Alimi ṣe dìtẹ̀gbàjọba lọ́wọ́ Afonja nítorí ẹ̀sìn
, Duration 4,54
01:27
Fídíò,
Ohun tó máa ń mú kí ọkùnrin máa rí àpẹrẹ pé òun lóyún nígbà tí ìyàwó rẹ̀ bá lóyún; COUVAD sydrome ni, ohun tó sì ń fàá rèé
, Duration 1,27
04:16
Fídíò,
Torí pé àwọn èèyàn ò rí ààrín èmi àti Allwell Ademola ni wọ́n fi ń sọ pé a ń fẹ́ra, àmọ́ Ọlọ́run yan án sínú ayé mi láti tọ́ mi sọ́nà – Rotimi Salami oṣere
, Duration 4,16
00:59
Fídíò,
Àwọn awakọ̀ ti bẹ̀rẹ̀ sí ní tò ra epo pẹ̀lú bí owó epo ṣe ń lọ sókè
, Duration 0,59
03:03
Fídíò,
Wo tọkọtaya tó ń gba àwẹ̀ Lent àti Ramadan papọ̀
, Duration 3,03
01:44
Fídíò,
Wo àkóbá tó wà nínú àgbàdo, ẹ̀wà àti ata tí a lọ̀ ní ẹ̀rọ ìlọta fún ẹ̀dọ̀ àti kíndìnrín rẹ
, Duration 1,44
05:52
Fídíò,
Ohun táwọn oníṣẹ̀ṣe sọ fún àjọ INEC lórí ìdìbò àti pàtàkì ọdún Ọ̀ṣun Osogbo tí wọ́n fi yí ọjọ́ ìdìbò gómìnà padà
, Duration 5,52
01:01
Fídíò,
Bí àwọn ọmọ orílẹ̀èdè Iran kan ṣe ń dunnú, làwọn míràn ń kẹ́dún lórí ikú Ayatollah Ali Khamenei olórí Iran
, Duration 1,01
01:20
Fídíò,
Fes el Bali, ìlú 'Mẹ́dínà kékéré' tí ẹ̀sìn àti àṣà ìṣẹ̀mbáyé ti pàdé ara wọn
, Duration 1,20
04:01
Fídíò,
Omi Arinta, omi ńlá tó máa ń yọ̀ nígbàkúgbà tó bá rí ènìyàn ní àyíká rẹ̀
, Duration 4,01
02:42
Fídíò,
Bí nǹkan oṣù rẹ̀ bá ń gba èékánná, ìdodo, àtẹ́lẹwọ́ àtàwọn ẹ̀yà ara tó yàtọ̀ sí ojú ara jáde, ọ̀nà àbáyọ rèé
, Duration 2,42
Trending Now