BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ọ́lọ́jọ́2018: Aṣọ ń pe aṣọ ránṣẹ́ nílé Ifẹ̀
29 Owewe 2018
Ìlú Ilé Ifẹ̀ sọkutu wọ̀wọ̀, tí ẹsẹ̀ kò sò gbèrò lásìkò ọdun Ọlọ́jọ́.
Àkọlé àwòrán,
Ẹni to ba kan ẹgbẹ awọn obinrin nibi ijoko wọn, yoo ki aje ku ikalẹ pẹlu asọ olowo iyebiye ti wọn ko si
Àkọlé àwòrán,
Onírúuru ẹgbẹ́jọda àṣọ làwọn ènìyàn wọ fún ayẹyẹ tó wọlé dé
Àkọlé àwòrán,
Ere òòdua rèé o tí tọka si ibi ti ọmọ Yorùba ti ṣẹ̀ wá
Àkọlé àwòrán,
Àwọn Isòrò ń dúró de Oònirìsà lati kìí fún ayẹyẹ ọdun Ọlọ́jọ
Àkọlé àwòrán,
Awọn awo lóbìnrin náà rèé láàyè wọn lati júba Ọ̀òni
Àkọlé àwòrán,
Gbàgede àyẹyẹ náà rèé oo, gbogbo ènìyàn ló ti wà ní ṣẹpẹ́
Àkọlé àwòrán,
Aafin Ọọni naa n sọkutu wọwọ fun ọdun Ọlọjọ
Àkọlé àwòrán,
Awọn ẹni bi ẹni, eeyan bii eeyan ko gbẹyin nibi ayẹyẹ ọdun Ọlọjọ
Àkọlé àwòrán,
Awọn Oloye naa joko sẹpẹ
Àkọlé àwòrán,
Asọ funfun ree to duro wawa lara awọn oloye
Àkọlé àwòrán,
Ẹ kore Yeye o
Àkọlé àwòrán,
Oju pe, ẹsẹ pele ni ọdun Ọlọjọ
Àkọlé àwòrán,
Awọn irun ibilẹ yii rẹwa, wọn jẹ oju ni gbese.
Àkọlé àwòrán,
Awọn ọmọ ilẹ okeere ko gbẹyin ni ọdun Ọlọjọ
Àkọlé àwòrán,
Oyinbp ree, to wọ asọ ibilẹ wa
Àkọlé àwòrán,
Ẹrin oyinbo yii nibi ọdun Ọlọjọ fa ni mọra
Àkọlé àwòrán,
Awọn Ajeji to wa sibi ọdun ọlọjọ kii se keremi
Àkọlé àwòrán,
Kabiyesi, Alayeluwa, Ọọni tilu Ifẹ ń ki àwọn araalu ku ọdun
Àkọlé àwòrán,
Awọn araalu n se Kabiesi si Ọọni
Móríwú
01:03
Fídíò,
Àwọn ọ̀dọ̀ ilẹ̀ Africa ni ìlera ọpọlọ wọn pé jù lọ láàgbáyé-Ìwádìí
, Duration 1,03
04:54
Fídíò,
Agboolé Akọni: Ohun tó fa ìjà láàárín Afonja àti Aláàfin Aole àti bí Alimi ṣe dìtẹ̀gbàjọba lọ́wọ́ Afonja nítorí ẹ̀sìn
, Duration 4,54
01:27
Fídíò,
Ohun tó máa ń mú kí ọkùnrin máa rí àpẹrẹ pé òun lóyún nígbà tí ìyàwó rẹ̀ bá lóyún; COUVAD sydrome ni, ohun tó sì ń fàá rèé
, Duration 1,27
04:16
Fídíò,
Torí pé àwọn èèyàn ò rí ààrín èmi àti Allwell Ademola ni wọ́n fi ń sọ pé a ń fẹ́ra, àmọ́ Ọlọ́run yan án sínú ayé mi láti tọ́ mi sọ́nà – Rotimi Salami oṣere
, Duration 4,16
00:59
Fídíò,
Àwọn awakọ̀ ti bẹ̀rẹ̀ sí ní tò ra epo pẹ̀lú bí owó epo ṣe ń lọ sókè
, Duration 0,59
03:03
Fídíò,
Wo tọkọtaya tó ń gba àwẹ̀ Lent àti Ramadan papọ̀
, Duration 3,03
01:44
Fídíò,
Wo àkóbá tó wà nínú àgbàdo, ẹ̀wà àti ata tí a lọ̀ ní ẹ̀rọ ìlọta fún ẹ̀dọ̀ àti kíndìnrín rẹ
, Duration 1,44
05:52
Fídíò,
Ohun táwọn oníṣẹ̀ṣe sọ fún àjọ INEC lórí ìdìbò àti pàtàkì ọdún Ọ̀ṣun Osogbo tí wọ́n fi yí ọjọ́ ìdìbò gómìnà padà
, Duration 5,52
01:01
Fídíò,
Bí àwọn ọmọ orílẹ̀èdè Iran kan ṣe ń dunnú, làwọn míràn ń kẹ́dún lórí ikú Ayatollah Ali Khamenei olórí Iran
, Duration 1,01
01:20
Fídíò,
Fes el Bali, ìlú 'Mẹ́dínà kékéré' tí ẹ̀sìn àti àṣà ìṣẹ̀mbáyé ti pàdé ara wọn
, Duration 1,20
04:01
Fídíò,
Omi Arinta, omi ńlá tó máa ń yọ̀ nígbàkúgbà tó bá rí ènìyàn ní àyíká rẹ̀
, Duration 4,01
02:42
Fídíò,
Bí nǹkan oṣù rẹ̀ bá ń gba èékánná, ìdodo, àtẹ́lẹwọ́ àtàwọn ẹ̀yà ara tó yàtọ̀ sí ojú ara jáde, ọ̀nà àbáyọ rèé
, Duration 2,42
Trending Now