BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Twins Festival: Asọ ń pe asọ ránsẹ́ lára àwọn ìbejì lásìkò ọdún wọn
13 Ọ̀wàrà 2018
Ẹsẹ̀ kò gbèrò ní ìlú Igbo ọrà lásìkò ọdún ìbejì àgbáyé tí ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ sètò.
Àkọlé àwòrán,
Ọdun ibeji agbaye sọkutu wọwọ ni ilu Igbo Ọra
Àkọlé àwòrán,
Ati agba ibeji, ati ọmọde ibeji ko gbẹ́yin nibi ọdun ibeji ni Igbo Ọra
Àkọlé àwòrán,
ijo ree lẹsẹ awọn ibeji, ti kọmisọna feto iroyin nipinlẹ Ọyọ, Toye Arulogun si n kọwọ rin pẹlu wọn
Àkọlé àwòrán,
Ankoo wa laa wọ lawọn ibeji yii se nibi ajọdun wọn ni Igbo Ọra
Àkọlé àwòrán,
Kọmisọna ree to n bawọn ibeji ya fọto nibi ajọdun ibeji Igbo Ọra
Àkọlé àwòrán,
Ajọdun ibeji agbaye yii ko yọ ẹlẹsin abi ọdọ silẹ, tọkunrin, tobinrin lo wa nibẹ
Àkọlé àwòrán,
Eyi wu wa o, awọn ọmọge ibeji ree o, ti wọn fi ilẹkẹ sọrun
Àkọlé àwòrán,
Ọmọde n bọ wa dagba, bi ẹyin ti n di akukọ. Awọn agba ibeji naa ree
Àkọlé àwòrán,
Awọn ibeji to ni ‘swagger‘ ree o, wọn ta san-san
Àkọlé àwòrán,
N jẹ ẹyin mọ iyatọ laarin awọn ibeji yii? N se ni wọn jọ ara wọn bii imumu
Àkọlé àwòrán,
Ọlọrun ma pa ibeji mi fun mi, ni adura ti baba yii n se lasiko to n bawọn ibeji rẹ ya fọto
Àkọlé àwòrán,
Awọn ibeji yii ma wu ni o, ejirẹ ara isokun
Àkọlé àwòrán,
Asọ kan naa, awọ kan naa, ila kan naa, koda, bakan naa ni awọn ibeji yii n wo. Ọlọrun ku isẹ rẹ
Àkọlé àwòrán,
Ẹni maa bi ibeji ko sẹwa wa, ọdun ibeji ko yọ awọn ibeji ọmọ ọwọ silẹ ni Igbo Ọra
Àkọlé àwòrán,
O ga ju. Ibeji alakọ lawọn eleyii. Ọlọrun ko ni pa yin fun wa
Àkọlé àwòrán,
Se ibeji ọmọ-ọba lawọn ibeji yii ni? Ilẹkẹ ọrun wọn gan n da ni lọrun
Àkọlé àwòrán,
Ọdun ibeji yii ko yọ awọn agba ibeji silẹ, a kii saa dagba ‘Malabẹ, eegun ẹran la le fọ’
Móríwú
01:03
Fídíò,
Àwọn ọ̀dọ̀ ilẹ̀ Africa ni ìlera ọpọlọ wọn pé jù lọ láàgbáyé-Ìwádìí
, Duration 1,03
04:54
Fídíò,
Agboolé Akọni: Ohun tó fa ìjà láàárín Afonja àti Aláàfin Aole àti bí Alimi ṣe dìtẹ̀gbàjọba lọ́wọ́ Afonja nítorí ẹ̀sìn
, Duration 4,54
01:27
Fídíò,
Ohun tó máa ń mú kí ọkùnrin máa rí àpẹrẹ pé òun lóyún nígbà tí ìyàwó rẹ̀ bá lóyún; COUVAD sydrome ni, ohun tó sì ń fàá rèé
, Duration 1,27
04:16
Fídíò,
Torí pé àwọn èèyàn ò rí ààrín èmi àti Allwell Ademola ni wọ́n fi ń sọ pé a ń fẹ́ra, àmọ́ Ọlọ́run yan án sínú ayé mi láti tọ́ mi sọ́nà – Rotimi Salami oṣere
, Duration 4,16
00:59
Fídíò,
Àwọn awakọ̀ ti bẹ̀rẹ̀ sí ní tò ra epo pẹ̀lú bí owó epo ṣe ń lọ sókè
, Duration 0,59
03:03
Fídíò,
Wo tọkọtaya tó ń gba àwẹ̀ Lent àti Ramadan papọ̀
, Duration 3,03
01:44
Fídíò,
Wo àkóbá tó wà nínú àgbàdo, ẹ̀wà àti ata tí a lọ̀ ní ẹ̀rọ ìlọta fún ẹ̀dọ̀ àti kíndìnrín rẹ
, Duration 1,44
05:52
Fídíò,
Ohun táwọn oníṣẹ̀ṣe sọ fún àjọ INEC lórí ìdìbò àti pàtàkì ọdún Ọ̀ṣun Osogbo tí wọ́n fi yí ọjọ́ ìdìbò gómìnà padà
, Duration 5,52
01:01
Fídíò,
Bí àwọn ọmọ orílẹ̀èdè Iran kan ṣe ń dunnú, làwọn míràn ń kẹ́dún lórí ikú Ayatollah Ali Khamenei olórí Iran
, Duration 1,01
01:20
Fídíò,
Fes el Bali, ìlú 'Mẹ́dínà kékéré' tí ẹ̀sìn àti àṣà ìṣẹ̀mbáyé ti pàdé ara wọn
, Duration 1,20
04:01
Fídíò,
Omi Arinta, omi ńlá tó máa ń yọ̀ nígbàkúgbà tó bá rí ènìyàn ní àyíká rẹ̀
, Duration 4,01
02:42
Fídíò,
Bí nǹkan oṣù rẹ̀ bá ń gba èékánná, ìdodo, àtẹ́lẹwọ́ àtàwọn ẹ̀yà ara tó yàtọ̀ sí ojú ara jáde, ọ̀nà àbáyọ rèé
, Duration 2,42
Trending Now