BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Àwọn abala
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìròyìn
Eré ìdárayá
Fídíò
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ẹ wo ohun tí ẹ̀kun omi dá nílùú Èkó
21 Ọ̀wàrà 2019
Ẹkun omi ti da ọpọlọpọ wahala silẹ kaakiri orilẹede Naijiria, ti ipinlẹ Eko naa si kun wọn.
Àkọlé àwòrán,
Omi ti gba ile mọ ọpọlọpọ lọwọ
Àkọlé àwòrán,
Ọpọ adugbo lo ti di alaini ina manamana nipasẹ alagbalugbu omi to gbale gbode nilu Eko
Àkọlé àwòrán,
Inu omi ni ọpọlọpọ olugbe n gba lọ sibi ijẹ wọn
Àkọlé àwòrán,
Ẹrọ amunawa pẹlu ti mu omi yo bamubamu
Àkọlé àwòrán,
Ọrọ ẹkun omi naa ko yọ olowo silẹ
Àkọlé àwòrán,
Ẹrọ amunawa pẹlu ti mu omi yo bamubamu
Àkọlé àwòrán,
Ọpọ awọn olugbe ni wọn ko mọ bi wọn yoo ṣe lọ sibi iṣẹ oojọ wọn
Àkọlé àwòrán,
Ọpọ awọn olugbe ni wọn ko mọ bi wọn yoo ṣe lọ sibi iṣẹ oojọ wọn
Àkọlé àwòrán,
Omi ti mu ọkọ akẹru yii nilu Eko
Àkọlé àwòrán,
Omi ti mu ọkọ akẹru yii nilu Eko
Àkọlé àwòrán,
Ọpọlọpọ dukia lo si ti ṣofo
Àkọlé àwòrán,
Omi ti gba ile mọ ọpọlọpọ lọwọ
Àkọlé àwòrán,
Omi ti gba ile mọ ọpọlọpọ lọwọ
Móríwú
01:03
Fídíò,
Àwọn ọ̀dọ̀ ilẹ̀ Africa ni ìlera ọpọlọ wọn pé jù lọ láàgbáyé-Ìwádìí
, Duration 1,03
04:54
Fídíò,
Agboolé Akọni: Ohun tó fa ìjà láàárín Afonja àti Aláàfin Aole àti bí Alimi ṣe dìtẹ̀gbàjọba lọ́wọ́ Afonja nítorí ẹ̀sìn
, Duration 4,54
01:27
Fídíò,
Ohun tó máa ń mú kí ọkùnrin máa rí àpẹrẹ pé òun lóyún nígbà tí ìyàwó rẹ̀ bá lóyún; COUVAD sydrome ni, ohun tó sì ń fàá rèé
, Duration 1,27
04:16
Fídíò,
Torí pé àwọn èèyàn ò rí ààrín èmi àti Allwell Ademola ni wọ́n fi ń sọ pé a ń fẹ́ra, àmọ́ Ọlọ́run yan án sínú ayé mi láti tọ́ mi sọ́nà – Rotimi Salami oṣere
, Duration 4,16
00:59
Fídíò,
Àwọn awakọ̀ ti bẹ̀rẹ̀ sí ní tò ra epo pẹ̀lú bí owó epo ṣe ń lọ sókè
, Duration 0,59
03:03
Fídíò,
Wo tọkọtaya tó ń gba àwẹ̀ Lent àti Ramadan papọ̀
, Duration 3,03
01:44
Fídíò,
Wo àkóbá tó wà nínú àgbàdo, ẹ̀wà àti ata tí a lọ̀ ní ẹ̀rọ ìlọta fún ẹ̀dọ̀ àti kíndìnrín rẹ
, Duration 1,44
05:52
Fídíò,
Ohun táwọn oníṣẹ̀ṣe sọ fún àjọ INEC lórí ìdìbò àti pàtàkì ọdún Ọ̀ṣun Osogbo tí wọ́n fi yí ọjọ́ ìdìbò gómìnà padà
, Duration 5,52
01:01
Fídíò,
Bí àwọn ọmọ orílẹ̀èdè Iran kan ṣe ń dunnú, làwọn míràn ń kẹ́dún lórí ikú Ayatollah Ali Khamenei olórí Iran
, Duration 1,01
01:20
Fídíò,
Fes el Bali, ìlú 'Mẹ́dínà kékéré' tí ẹ̀sìn àti àṣà ìṣẹ̀mbáyé ti pàdé ara wọn
, Duration 1,20
04:01
Fídíò,
Omi Arinta, omi ńlá tó máa ń yọ̀ nígbàkúgbà tó bá rí ènìyàn ní àyíká rẹ̀
, Duration 4,01
02:42
Fídíò,
Bí nǹkan oṣù rẹ̀ bá ń gba èékánná, ìdodo, àtẹ́lẹwọ́ àtàwọn ẹ̀yà ara tó yàtọ̀ sí ojú ara jáde, ọ̀nà àbáyọ rèé
, Duration 2,42
Trending Now