Nigerian Labour Congress: Diẹ rèé nínú àwòrán ìwọ́de àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ Nàìjíríà ní Abuja, Eko àti Ibadan

Ohun tawọn oṣiṣẹ lawọn fẹ ni pe ki ile aṣofin ma gbe aṣẹ sisan owo oṣu kuro ni abẹ ijọba apapọ lọ si abẹ aṣẹ ijọba ipinlẹ.

Iwọde ẹgbẹ oṣiṣẹ
Àkọlé àwòrán, Iwọde ni Abuja
Iwọde ẹgbẹ oṣiṣẹ
Àkọlé àwòrán, Iwọde ẹgbẹ oṣiṣẹ
Iwọde ẹgbẹ oṣiṣẹ
Àkọlé àwòrán, Iwọde ni Abuja
Iwọde ẹgbẹ oṣiṣẹ
Àkọlé àwòrán, Iwọde ẹgbẹ oṣiṣẹ
Aworan oluwọde NLC
Àkọlé àwòrán, Awọn ọmọ ẹgbẹ NLC nilu Ibadan naa tu yaya jade lati ṣe iwọde
Aworan oluwọde NLC
Àkọlé àwòrán, Ohun tawọn oṣiṣẹ lawọn fẹ ni pe ki ile aṣofin ma gbe aṣẹ sisan owo oṣu kuro ni abẹ ijọba apapọ lọ si abẹ aṣẹ ijọba ipinlẹ
Aworan oluwọde NLC
Àkọlé àwòrán, NLC sọ pe ti wọn ba gbe aṣẹ yi kuro labẹ aṣẹ ijọba apapọ, awọn ipinlẹ le maa san iye to ba wu wọn foṣiṣẹ
Aworan oluwọde NLC
Àkọlé àwòrán, Aarẹ awọn oṣiṣẹ Ayuba Waaba ni ailanu ara ilu loju lo mu ki awọn aṣofin fẹ gbe igbesẹ yi
Aworan oluwọde NLC
Àkọlé àwòrán, Nilu Eko ti o jẹ olu ilu ọrọ aje Naijiria awọn oṣiṣẹ gba oju titi lati se iwọde
Iwọde ẹgbẹ oṣiṣẹ
Àkọlé àwòrán, Iwọde ni ilu Abuja
Aworan oluwọde NLC
Àkọlé àwòrán, Ọrọ owo oṣu to kere julọ lorileede Naijiria jẹ eleyi ti o fọwọ kan ọpọ oṣiṣẹ lẹmi