Ohun tó máa ń mú kí ọkùnrin máa rí àpẹrẹ pé òun lóyún nígbà tí ìyàwó rẹ̀ bá lóyún; COUVAD sydrome ni, ohun tó sì ń fàá rèé

Àkọlé fídíò, Ohun tó máa ń mú kí ọkùnrin máa rí àpẹrẹ pé òun lóyún nígbà tí ìyàwó rẹ̀ bá lóyún; COUVAD sydrome ni, ohun tó sì ń fàá rèé
Ohun tó máa ń mú kí ọkùnrin máa rí àpẹrẹ pé òun lóyún nígbà tí ìyàwó rẹ̀ bá lóyún; COUVAD sydrome ni, ohun tó sì ń fàá rèé

Njẹ o mọ pe o ṣeeṣe ki ọkunrin maa ri apẹrẹ pe oun loyun lasiko ti iyawo rẹ ba loyun?

Bẹẹni, COUVAD syndrome lawọn oloyinbo atawọn onimọ iṣegun oyinbo n pe e.

Lara awọn apẹrẹ oyun ti ọkunrin lee maa ri niru asiko bẹẹ ni bii pe ko maa bi, ko maa sanra tabi ko ma le e jẹun daadaa.

Igba miran awọneroja pipe ara ti oyinbo n pe ni 'homones' ninu agọ ara rẹ pẹlu lee maa mu ayipada jade si ohun to ti wa tẹlẹ ni agọ ara arakunrin naa lasiko ti ololufẹ rẹ ba loyun. Kii ṣe ọkunrin yii loyun o ṣugbọn oun lo n ri awọn apẹrẹ oyun.

Alaye ohun aramanda yii wa ninu fidio yii.