Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

À n ṣiṣẹ́ kárakára láti dáàbò bò àwọn èèyàn Kwara

Kọmiṣanna ọlọ́pàá Kwara Adekimi Ojo lo fi awọn eeyan Kwara lọkan balẹ bẹẹ

O ni awọn agbofinro n ṣiṣẹ karakara lati fopin si iṣoro eto aabo to n koju ipinlẹ naa lasiko yii.

Ileeṣẹ ọlọpaa Kwara sọ eyi lẹyin iṣẹlẹ ibugbamu ado oloro to waye agbegbe Woro nijọba ibilẹ Kaiama

Ẹkunrẹrẹ iroyin naa wa loju opo wa

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Emi ṣi ni ààrẹ àpapọ̀ fún ẹgbẹ́ àwọn onímọ́tò, NURTW

Musiliu Ayinde Akinsanya tí ọ̀pọ̀ mọ̀ sí MC Oluomo ló sọ̀rọ̀ yìí lẹ́yìn tí ìròyìn gbòde lọ́jọ́ Ajé

Pé ikọ̀ Baruwa yawọ ilé ẹgbẹ́ náà tó wà ní ìlú Abuja láti gbàkóso ẹgbẹ́ náà

Ṣé lóòótọ́ wá ni pé àwọn ọlọ́pàá ṣíná ìbọn bolẹ̀ níbẹ̀?

Kà á lójú òpó bbc.com/Yoruba

xxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx

Ǹjẹ́ o mọ̀ pé àwọn kan ń jèrè lórí ogun ti Amẹ́ríkà àti Israel ń gbe ti Iran?

Ṣé pẹ̀lú bí àwa kan ṣe ń kojú ọ̀wọ́ngógó epo bẹntiróòlú yìí náà

Bẹ́ẹ̀ ni o àmọ́ báwọn kan ṣe ń jèrè làwọn míì ń pàdánù

Àwọn wo ló wá ń jèrè àwọn wo lò ń pàdánù?