DJ Cuppy ṣàlàyé ìdí tí inú rẹ̀ fi dùn pé Ààrẹ Tinubu ṣàbẹ̀wò sí ilẹ̀ UK
DJ Cuppy ṣàlàyé ìdí tí inú rẹ̀ fi dùn pé Ààrẹ Tinubu ṣàbẹ̀wò sí ilẹ̀ UK
Ifeoluwa Florence Otedola, ọmọ baba olowo, Femi Otedola ti ọpọ mọ si DJ Cuppy ba BBC News lori ipa abẹwo Aarẹ Bola Tinubu ati iyawo rẹ, Oluremi Tinubu si ilẹ UK fun ọjọ meji.
Bẹẹ ba gbagbe, Aarẹ Tinubu ati Iyawo rẹ, Oluremi Tinubu ṣe abẹwo si ilẹ UK lati ki Ọba Charlse III ni ọsẹ yii.
Abẹwo ọlọjọ meji naa ni akọkọ iru rẹ lati bi ọgbọn ọdun sẹyin lasiko iṣejọba ologun Ibrahim Babangida.
DJ Cuppy ni abẹwo yii ki n ṣe ajọsepọ nikan ṣugbọn fun ilọsiwaju ilu mejeeji ati pe Ilẹ Uk yii ni ọpọ ọmọ Naijiria pọ si lagbaye.
"Asiko yii jẹ asiko nla fun mi lati ṣe ayẹyẹ ohun ti mo fẹran nipa orilẹede mejeeji ti mo n lo si ju."







