Ojude Ọba 2019: Àwọn èèkàn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti péjú fún ayẹyẹ ojúde Ọba Àkọlé àwòrán, Ojude Oba tí ọdún yìí ti gbéra sọ pẹ̀lú oníruuru àwọn aṣọ alárànbara yorùba to ń wúni lóri, Awọn ẹgbẹ́ Tobalàṣẹ obinrin rèé nínú àṣọ okè aláwọ̀ ewé 13 Ògún 2019
Àkọlé àwòrán, Gbogbo àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Gbobaniyi lókùnrin àti lóbìrin ló ti lọ ki ọba aláde lóri ìjòkò Àkọlé àwòrán, Lẹ́gbẹ́ lẹ́gbẹ́ ni gbogbo àwọn ti wọ́n péju síbi ayéyé Ojude Oba tí ọdún 2019 Àkọlé àwòrán, Tokùnrin tobinrin ló wọsọ ìgbà níbi àyẹyẹ ojude oba tọdún yìí, Ẹgbẹ́ Bọbakẹ́yẹ Ọkunrin ni àwọn yìí Àkọlé àwòrán, Tarúgbó tomidàn ló wà nibi àyẹyẹ yìí, gbogbo oju wọ́n lo gúrégé pèlú, àwọn ẹgbẹ́ bọ́bakẹ́yẹ obinrin rèé Àkọlé àwòrán, Gbogbo àwọn olóyè àti èèkàn ìlú ló péjú Àkọlé àwòrán, Kìí ṣe àwọn ẹgbẹ́ gbẹ́ jọdá nìkàn ló péju, àwọn ọdọ náà jáde wá láti yẹ́ àṣ]a ìbílẹ̀ sí Àkọlé àwòrán, Aláàfin Ọyọ, ikú bábá yèyé, Ọba Lamidi Adeyemi náà péjú síbi ayẹyẹ ojúde Oba ní'lú Ijebu Àkọlé àwòrán, Gómínà ìpínlẹ̀ Ogun, Dapo Abiodun àti Awùjalẹ̀ Ijẹ̀bú Ọba Sikiru Adetona Àkọlé àwòrán, Gómìnà tẹ́lẹ̀rí ní ìpínlẹ̀ Ogun, Ọtunba Gbẹnga Daniels Àkọlé àwòrán, Ẹgbẹ́ Bọ́baguntẹ ilẹ̀ Ijẹbu Àkọlé àwòrán, Gbogbo ojú tó ti ríra típẹ tún ni àànfàni láti ṣe "Ẹ k;u àti" Àkọlé àwòrán, Ẹgbẹ́ Obafunwaji Obinrin Adedoyin rèé nínú aṣọ ofi aláwọ̀ búlù Àkọlé àwòrán, Ẹgbẹ́ Tobalaṣẹ Ọkunrin náà ko gbẹ́yìn Àkọlé àwòrán, Gbogbo àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Gbobaniyi lókùnrin àti lóbìrin ló ti lọ ki ọba aláde lóri ìjòkò Móríwú Fídíò, Mọ̀ nípa àwọn ewu méje tó rọ̀ mọ́ ṣíṣe ìdí ńlá, BBL, àti ìlànà tí wọ́n ń gbà ṣe é , Duration 1,13 Fídíò, Àwọn ọ̀dọ̀ ilẹ̀ Africa ni ìlera ọpọlọ wọn pé jù lọ láàgbáyé-Ìwádìí , Duration 1,03 Fídíò, DJ Cuppy ṣàlàyé ìdí tí inú rẹ̀ fi dùn pé Ààrẹ Tinubu ṣàbẹ̀wò sí ilẹ̀ UK , Duration 1,57 Fídíò, Ìlú kan rèé lábẹ́ ìjọba Ogun àmọ́ ilẹ̀ Benin ni wọn ti ń bímọ, pọn omi, ta ọjà pẹ̀lú ìnira ńlá , Duration 4,18 Fídíò, Agboolé Akọni: Ohun tó fa ìjà láàárín Afonja àti Aláàfin Aole àti bí Alimi ṣe dìtẹ̀gbàjọba lọ́wọ́ Afonja nítorí ẹ̀sìn , Duration 4,54 Fídíò, Ohun tó máa ń mú kí ọkùnrin máa rí àpẹrẹ pé òun lóyún nígbà tí ìyàwó rẹ̀ bá lóyún; COUVAD sydrome ni, ohun tó sì ń fàá rèé , Duration 1,27 Fídíò, Torí pé àwọn èèyàn ò rí ààrín èmi àti Allwell Ademola ni wọ́n fi ń sọ pé a ń fẹ́ra, àmọ́ Ọlọ́run yan án sínú ayé mi láti tọ́ mi sọ́nà – Rotimi Salami oṣere , Duration 4,16 Fídíò, Àwọn awakọ̀ ti bẹ̀rẹ̀ sí ní tò ra epo pẹ̀lú bí owó epo ṣe ń lọ sókè , Duration 0,59 Fídíò, Wo tọkọtaya tó ń gba àwẹ̀ Lent àti Ramadan papọ̀ , Duration 3,03 Fídíò, Wo àkóbá tó wà nínú àgbàdo, ẹ̀wà àti ata tí a lọ̀ ní ẹ̀rọ ìlọta fún ẹ̀dọ̀ àti kíndìnrín rẹ , Duration 1,44 Fídíò, Ohun táwọn oníṣẹ̀ṣe sọ fún àjọ INEC lórí ìdìbò àti pàtàkì ọdún Ọ̀ṣun Osogbo tí wọ́n fi yí ọjọ́ ìdìbò gómìnà padà , Duration 5,52