Lẹ́yìn ìpàdé àpapọ̀ l'Abuja, wo àwọn tí yóó tukọ̀ APC fọ́dún mẹ́rin

Oríṣun àwòrán, APC
Ọjọ Ẹti ati ọjọ Abamẹta ana ni ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC) fi ẹnu ọrọ jona lori awọn ti yoo tukọ ẹgbẹ naa fun ọdun mẹrin, lẹyin ipade apapọ ẹgbẹ naa to waye l'Abuja.
Nibi ipade ọhun ni wọn tun ti yan Alaga apapọ wọn, Nentawe Yilwatda ati Ajibola Basiru pada sipo alaga ati Akọwe apapọ ẹgbẹ APC.
Afẹnuko to waye lati yan awọn eeyan naa tẹsiwaju, nigba ti wọn tun yan awọn alakoso APC miran nibi eto ti Aarẹ ilẹ wa, Bola Tinubu naa wa.
Eyi ni awọn oloye ẹgbẹ APC naa
Alaga Apapọ: Ọjọgbọn Nentawe Yilwatda.
Igbakeji Alaga apapọ: (Ariwa) Ali Bukar Dalori.
Igbakeji Alaga apapọ (Guusu: Ọmọwe Benjamin Obi Nwoye.
Akọwe Apapọ: Senetọ Surajudeen Ajibola Basiru.
Igbakeji Akọwe apapọ: Ọjọgbọn AbdulKarim Abubakar Kana.
Amofin ẹgbẹ lapapọ: Murtala Aliyu Kankia.
Akapo ẹgbẹ apapọ: Uguru Mathew Ofoke
Akọwe owo apapọ: Amb. Haruna Ginsau.
Akọwe eto apapọ: Muhammad Sulaiman Argungu.
Igbakeji Akọwe ẹgbẹ apapọ: Barr. Emeka Okafor
Akọwe igbayegbadun: Donatus Enyinnah Nwankpa.
Igbakeji Akọwe igbayegbadun: Ọmọwe Christopher Michael Akpan.
Awọn miran ni:
Akọwe ipolongo: Felix Morka.
Igbakeji Akọwe ipolongo:Ọnarebu Meseko Durosinmi Josiah.
Ayẹwe owo wo apapọ: Senetọ Abubakar Maikafi.
Olori awọn obinrin ẹgbẹ lapapọ: Ọmọwe Mary A. Idele
Igbakeji olori awọn obinrin ẹgbẹ lapapọ: Zainab Abubakar Ibrahim.
Olori ọdọ lapapọ: Dayo Israel.
Olori ẹgbẹ awọn Akanda ẹda lapapọ: Aarẹ Durotolu Oyebode Bankole.
Igbakeji Akọwe ẹgbẹ Hammam Adamu Ali Kumo.
Awọn alabojuto:
Aarin Gbungbun Ariwa: Ọmọwe Opawoye Oluwatoyin Bunmi.
Ariwa Ila-Oorun: Adamu Jallah.
Ariwa Iwọ-Oorun: Kano Muhammed Jamu Yusuf.
Guusu Ila-Oorun: Ọnarebu Ikechukwu Umeh.
Guusu-Guusu: Ọgbẹni Francis Kolokolo.
Guusu Iwọ-Oorun: Onarebu Bunmi Orinowo

























